Njẹ iwọ n wa ọna lati ba wa ṣiṣẹ gẹgẹ bi akọroyin ni eyikeyi ilu ti o ba wa, tabi o wu ẹ lati jẹ ọkan
lara awọn oludamọnran wa, aaye ti ṣi silẹ bayii fun un yin lati darapọ mọ wa.
Bo si jẹ pe ẹ fẹ ẹ fi iroyin awọn iṣẹlẹ to n ṣẹlẹ ladugbo tabi lagbegbe yin to wa leti ni, ilẹkun ṣi silẹ.
No comments:
Post a Comment