Ijọba Kwara gba ẹgbẹrun mejidin-diẹ olukọ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, January 9, 2025

Ijọba Kwara gba ẹgbẹrun mejidin-diẹ olukọ


Ijọba ipinlẹ Kwara ti kede pe ohun ti gba olukọ ati oṣiṣẹ ti to din diẹ ni ẹgbẹ meji (1,811) fun si awọn ile-ẹkọ ijọba kaakiri ipinlẹ naa.

Awọn to din diẹ ni ẹgbẹrun mẹrindinlọgọta (55,713) ni wọn forukọ silẹ fun iṣẹ olukọ ninu fọọmu tijọba gbe jade lọdun to kọja.

Ṣugbọn ajọ to n ri sọrọ eto ẹkọ alakọbẹrẹ nipinlẹ naa, Kwara State Universal Basic Education Board (KWSUBEB) sọ pe awọn 1,811 pere ni wọn peregede fun ipele to kan.

Wọn ni ẹgbẹrun kan aabọ ni awọn olukọ ti wọn peregede, nigba ti awọn ọọdun le ni mọkanla lawọn ti yoo jẹ oṣiṣẹ lawọn ile-ẹkọ naa, bii alagbawa, oṣiṣẹ alaabo, ati awọn oluranlọwọ lawọn ofiisi.

Kaakiri ile-ẹkọ alakọbẹrẹ to wa nijọba ibilẹ mẹrindinlogun naa ni wọn yoo ti ṣiṣẹ.

Ọjọ Aje, ọsẹ yii ni ajọ KWSUBEB sọ pe eto iforukọsilẹ bẹrẹ ni pẹrẹ pẹlu awọn ti ijọba ibilẹ Ariwa Kwara, nigba ti awọn tijọba ibilẹ Guusu yoo ṣe tiwọn lọjọ keje.

Awọn ti ẹkun aarin gbungbun Kwara yoo ṣe lọjọ kẹjọ.

Ọjọgbọn Sheu Raheem Adaramaja to jẹ alaga KWSUBEB ṣalaye pe gbogbo awọn ti wọn yege patapata ni wọn yoo ko awọn iwe ẹri idanimọ ati eto ẹkọ wọn silẹ fun iforukọsilẹ lẹkunrẹrẹ.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI