Ogbontairigi oniwaai agbaye nni, Sheik Muyideen Ajani Bello ti jade laye.
Aarọ oni, ọjọ Ẹti ni iroyin iku agba ẹlẹsin Musulumi naa jade sita.
Ilu Ibadan ni baba naa to fi ilu Ibadan, ipinlẹ Ọyọ ṣebugbe.
Lara awọn to fi iroyin iku naa to wa leti jẹ ko ye wa pe baba naa ti n ṣaisan lati bi ọsẹ meloo kan sẹyin, ko to di pe ẹlẹmi gba a.
Alaaji Basit Ọlanrewaju Katibi Bello tọpọ mọ si Apọnle Anọbi lo kede iroyin iku agba ẹlẹsin naa lori ikanni Facebook laipẹ yii.
No comments:
Post a Comment