Akẹkọọ '3MTT' ipele keji kẹkọọgboye pẹlu ẹbun owo ni Kwara - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Monday, December 9, 2024

Akẹkọọ '3MTT' ipele keji kẹkọọgboye pẹlu ẹbun owo ni Kwara


Ipele keji awọn akẹkọọ '3 Million Technical Talents (3MTT)' ni wọn ti kẹkọọgboye pẹlu ẹbun owo lati fi bẹrẹ okoowo wọn.

3MTT naa jẹ agbekalẹ ijọba apapọ, eyi ti ijọba Kwara ṣagbatẹru ẹ lati ṣe iranwọ fawọn ọdọ.

Gomina AbdulRahman AbdulRazaq sọ pe ipinnu agbekalẹ naa ni lati ṣagbelarugẹ fun imọ ẹrọ ati eto ọrọ aje.











No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI