Aarẹ ilẹ Naijiria, Bọla Ahmẹd Tinubu lo ti balẹ siluu Cape Town lorileede South Afrika fun akanṣe eto ti wọn pe ni Nigeria-South Africa Bi-National Commission (BNC).
Minisita fọrọ ibaṣepọ ilẹ okeere, Roland Lamola pẹlu minisita fọrọ ilẹ okeere ni Naijiria, Bianca Odumegwu-Ojukwu lo lọ pade aarẹ ni papakọ ofurufu.
Diẹ ree lara awọn aworan bi wọn ṣe pade Aarẹ Tinubu.
No comments:
Post a Comment