Ìjọba Kwara ṣe ìlérí ìrànlọ́wọ́ tuntun fàwọn ọ̀dọ́, lẹ́yìn àṣeyọrí Ẹniọla lágbayé - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Monday, September 9, 2024

Ìjọba Kwara ṣe ìlérí ìrànlọ́wọ́ tuntun fàwọn ọ̀dọ́, lẹ́yìn àṣeyọrí Ẹniọla lágbayé


Ijọba ipinlẹ Kwara tun ti ṣeleri pe ohun yoo tubọ maa ṣe iranlọwọ to tọ fun awọn ọdọ ipinlẹ naa, pẹlu erongba lati maa gbe ogo ipinlẹ ọhun ga kaakiri.

Ọrọ yii lo waye lẹnu ọkan lara awọn alẹnulọrọ ninu ijọba nigba ti wọn lọ pade Ẹniọla Bọlaji Mariam to gba ife ẹyẹ goolu agbaye laipẹ yii.

Mariam, ọmọ bibi ipinlẹ Kwara lo ṣe ipo kinni nibi ẹka ere idaraya Badminton lagbaye, ninu idije Paris 2024 Paralympics.





No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI