Ọ̀ọni Ifẹ̀ yan gbajúmọ̀ oníṣòwò gẹ́gé bíi Baṣọ̀run Àgba Akin ilẹ̀ Yorùbá - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, August 29, 2024

Ọ̀ọni Ifẹ̀ yan gbajúmọ̀ oníṣòwò gẹ́gé bíi Baṣọ̀run Àgba Akin ilẹ̀ Yorùbá


Ọọni Ile-Ifẹ, Oba Adeyẹyẹ Ẹnitan Ogunwusi lo ti yan gbajugbaja oniṣowo ilẹ ati dukia nni, Oloye Waheed Ọlanṣile Alexandria, gẹgẹ bii Baṣọrun Agba-Akin ilẹ Yoruba.

Ọba Ogunwusi lo jawe oye le Oloye Silẹ Alexandria lori ninu aafin rẹ to wa niluu Ile-ifẹ, to jẹ orirun ilẹ Yoruba lapapọ l'Ọjọru, ọjọ kejidinlọgbọn, oṣu kẹjọ, ọdun 2024.

Oloye Alexandria ni alaṣẹ ati oludasilẹ ileeṣẹ Alexander Properties kaakiri orileede Naijiria ati agbegbe rẹ, pẹlu ontẹ ijọba.

Niṣe ni gbogbo ilu Ile-Ifẹ di gaga nigba ti awọn ololufẹ agba oniṣowo naa n joye yii, pẹlu bi wọn ṣe lọ ba a yọ.

Diẹ ree lara bi eto ọhun ṣe lọ...
 


 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI