Ìjọba Kwara pín àwọn ohun ọ̀gbìn fáwọn àgbẹ̀ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Wednesday, August 28, 2024

Ìjọba Kwara pín àwọn ohun ọ̀gbìn fáwọn àgbẹ̀


Ijọba ipinlẹ Kwara tun ti pin awọn ohun ọgbin fun awọn agbẹ miran nipinlẹ naa.

Lojuna lati mu opin de ba iṣoro aisi ati ọwọngogo ounjẹ, eyi ti ijọba Kwara ṣagbekalẹ rẹ lọdun to kọja, ni wọn ti bẹrẹ sii pin awọn ohun ọgbin fun wọn.

Awọn agbẹ to wa ni ijọba ibilẹ Ekiti ni wọn tun jẹ anfaani ọhun lonii.

Ipele kẹta ree ninu awọn agbẹ ẹgbẹrun mẹwaa ti ijọba ni erongba lati ro lagbara kaakiri ijọba ibilẹ mẹẹdogun to wa nipinlẹ naa.




No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI