Afárá Unity ti dé ipele láti parí - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Monday, August 19, 2024

Afárá Unity ti dé ipele láti parí


Ijọba ipinlẹ Kwara ti kede wi pe afara agbegbe Unity ti Gomina AbdulRahman AbdulRazaq bẹrẹ ti de ipele lati pari fun lilo araalu.

A gbọ pe gbogbo ilana ati eto ti wọn gbe kalẹ lati jẹ ki afara naa pari, ni awọn agbaṣẹṣe n tẹle loore-koore.

Eyii si ni lara awọn ipinnu ati agbekalẹ Gomina AbdulRahman AbdulRazaq lati mu idagbasoke ati ilọsiwaju ba ipinlẹ naa lọna igbalode.







No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI