Àwa gangan ni MFM Pastor teleri, Femi Jimoh wá bá wípé ká ran òun lọwọ lati digun ja ijo MFM ló'lè - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Monday, July 15, 2024

Àwa gangan ni MFM Pastor teleri, Femi Jimoh wá bá wípé ká ran òun lọwọ lati digun ja ijo MFM ló'lè


Gbọ ọrọ láti ẹnu àwon alami ti ọlọ́pàá lo lati fi ọwọ ṣìkún òfin mu pasito MFM tẹlẹ rí, Femi Jimoh.

Iwọ na wo orísirísi irọ rabande ti Fẹmi Jimoh pa mọ ijo MFM at'awọn míràn, nínú fídíò yìí.


No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI