Adron Is The Biggest: Agbekalẹ nla to n lewaju ninu lagboole okoowo ile gbigbe lorileede Naijiria - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Monday, July 15, 2024

Adron Is The Biggest: Agbekalẹ nla to n lewaju ninu lagboole okoowo ile gbigbe lorileede Naijiria


Bi wọn ba n darukọ ileeṣẹ to n mu irọrun, ifọkanbalẹ ati alaafia ba araalu, to si n sọ gbogbo eeyan di onile lori, ọkan pataki ni ileeṣẹ Adron Homes and Properties Limited.

Odu ni ileeṣẹ Adron Homes nibi ka ta ile, ilẹ, ka tun ba ni kọle to jọju ni Naijiria, wọn kii ṣaimọ foloko.

Lati ọdun 2012 ti ileeṣẹ naa ti wa, ni wọn ti gbẹrẹgẹjigẹ, ti wọn si ti wa niwaju, eyi to mu ki awọn eeyan maa sọ pe 'ADRON IS THE BIGGEST'.

Agbekalẹ nla to n lewaju ni gbogbo ọna lagboole ile gbigbe ni Adron Homes jẹ, nitori pe pẹlu ifọkanbalẹ ni awọn onibara wọn fi n gbe ninu ile ati dukia ti wọn ra lọwọ wọn.

Ẹ ka nipa ileeṣẹ yii siwaju sii
 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI