Adron Homes: Ileeṣẹ to n di alafo laarin olowo ati mẹkunu - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Monday, July 15, 2024

Adron Homes: Ileeṣẹ to n di alafo laarin olowo ati mẹkunu


Yoruba bọ, wọn ni, olowo kan laarin otoṣi mẹfa...ẹyin ni ki ẹ pari ẹ nitoripe awa ko mọ ọn.

Bi wọn ba n darukọ awọn ileeṣẹ to ni afojusun rere fun araalu, paapaa ọmọ Naijiria lapapọ, ọkan pataki ni ileeṣẹ Adron Homes and Properties Limited nilẹ yii.

Adron Homes lo n sọ ayalegbe di onile lori lojiji lai nii ṣe pẹlu iru iṣẹ ti ayalegbe ọhun yan laayo.

Ni ibamu pẹlu ipinnu ajọ iṣọkan agbaye, iyẹn United Nations lati ṣakọsilẹ awọn ipenija to n de ba bi awọn eeyan ṣe n pọ lagbaye, paapaa ni ti igbe aye irọrun wọn lo lọ ni ibamu pẹlu afojusun ileeṣẹ Adron Homes.

Lara awọn ipenija naa ni pe pupọ awọn eeyan ni ko ni ile lori, idi ree ti ọrọ ile gbigbe fi jẹ Adron Homes logun, ti wọn si n fẹ ki gbogbo eeyan di onile lori.

Lara awọn anfaani to wa nileeṣẹ Adron Homes ni pe owo wọn ko ga ni lara. Gbogbo awọn lọ sibẹ pẹlu iyemeji ni wọn n ri ohun to n ṣẹlẹ pe olotitọ ni wọn.

Wọn ko si ninu igbo kijikiji: Ọpọ awọn ti wọn l'awọn n ta ilẹ lo jẹ pe irọ ni wọn n pa, ati pe inu igbo kijikiji ni wọn wa, ṣugbọn ti ileeṣẹ Adron Homes ko ri bẹẹ.

Aarin ilu ni awọn ilẹ ati dukia wọn wa, eyi to fi n jẹ irọrun lati mu onibara lọ.

Ileeṣẹ Adron Homes ni ilẹ, ile ati dukia si awọn agbegbe bii Ibeju-Lekki, Epe, Badagry, Shimawa, Atan-Ota, Ikorodu, Shagamu, Papalanto, Ijebu Ode, Abeokuta, Ibadan, Ado Ekiti, Osun, Jos, Abuja, Nasarawa, ati Niger.

Bi ẹ ba fẹẹ mọ sii lẹkunrẹrẹ, ẹ kan si wọn bayii

Ẹrọ ibanisọrọ: 08138432335
Oju opo ayelujara: adronhomesproperties.com

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI