Iṣẹ akanṣe opopona Township si Igbaja ni Kwara ti fẹẹ pari - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Wednesday, April 3, 2024

Iṣẹ akanṣe opopona Township si Igbaja ni Kwara ti fẹẹ pari


Ijọba ipinlẹ Kwara ti sọ pe opopona Township Hall si Igbaja ti de ipele to ti fẹẹ pari fun lilo araalu.

Gẹgẹ bi a ṣe gbọ, wọn ni ọda dudu to gbẹyin ni wọn yoo da lonii.

Opopona naa yoo mu irọrun ba igbokegbodo ọkọ ati idagbasoke ba eto ọrọ aje ipinlẹ Kwara.





No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI