Iroyin to n lọ kaakiri igboro ipinlẹ Kwara bayii ni pe owo irẹsi ti ja lọ silẹ patapata si iye owo ti wọn n ta tẹlẹ.
Eyii lo si fa idunnu araalu wi pe igba ọtun ti n bọ diẹdiẹ.
Tẹlẹtẹlẹ, ẹgbẹrun lọna ọgọrin naira ni wọn n ta baagi irẹsi tẹlẹ, ṣugbọn ni bayii, ẹgbẹrun mẹrinlelaadọta ni wọn n ta a, gẹgẹ bi a ṣe gbọ
No comments:
Post a Comment