Agogo mẹrin ku iṣẹju mọkandinlọgbọn, 3:39pm, ọjọ Ẹti, Fraide, ọjọ karun-un, oṣu kinni, ọdun 2024 ni wọn gbe oku naa de.
Iyawo rẹ, Betty Anyanwu-Akeredolu; awọn ọmọ ati awọn mọlẹbi ti Ọjọgbọn Wọle Akeredolu to jẹ aburo oloogbe lo lọ pade oku naa ni papakọ ofurufu.
Iyawo rẹ, Betty Anyanwu-Akeredolu; awọn ọmọ ati awọn mọlẹbi ti Ọjọgbọn Wọle Akeredolu to jẹ aburo oloogbe lo lọ pade oku naa ni papakọ ofurufu.
Ọjọ kẹtadinlọgbọn, oṣu kejila, ọdun 2023 ni Akeredolu dagbere faye lẹyin aisan jẹjẹrẹ to ba a finra fun ọjọ pipẹ.
No comments:
Post a Comment