Awọn agba olori meji nni, Ṣẹfiu Alao Adekunle ti ọpọ awọn eeyan mọ si Baba Oko ati gbajugbaja olorin musulumi nni, Alaaji Abdul-Kabir Bukola Alayande ti awọn ololufẹ rẹ mọ si Ere Asalatu ni wọn ti jọ wọ yara igbohunsilẹ fun akọtun ori ajọkọ ti wọn n pe ni kolabo.
Unusual Collaboration: Fuji Star, Sefiu Alao And Islamic Music Star, Ere Asalatu, Hit The Studio For Joint Album
Ile orin Zeal Mark Sound Studio to wa lagbegbe Ansar-Ud-Deen loju ọna Quarry niluu Abẹokuta ni wọn ti n po awọn orin naa papọ, gẹgẹ bi a ṣe gbọ.
Iroyin to té wa lọwọ sọ pe orin naa yoo mi gbogbo igboro titi to ba di pe o jinna tan, to si jade sita.
No comments:
Post a Comment