Alagba Ọlanrewaju Adepọju ti jade laye lẹni ọdun mẹtalelọgọrin (83).
Ọkan lara awọn ọmọ rẹ, Adejare Adepọju lo kede iku baba yii lọjọ Aiku, Sannde to kọja, ọjọ kẹwaa, oṣu kejila, ọdun 2023.
Nnkan bi agogo meje irọlẹ ni baba naa dagbere faye pe o digboṣe.
No comments:
Post a Comment