Aarẹ Ọna Kakanfo gbe iyawo tuntun, Joy lorukọ ẹ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Tuesday, December 12, 2023

Aarẹ Ọna Kakanfo gbe iyawo tuntun, Joy lorukọ ẹ


Aarẹ Ọna Kakanfo ilẹ Yoruba, Ib Abidọdun Ige Gani Adams ti fẹ iyawo tuntun.

Gbajugbaja arẹwa ọmọ bibi ipinlẹ Delta, Joy Onojaife to ti figb kan ri gba aami ẹyẹ omidan to rẹwa julọ ni Aarẹ Ọna Kakanfo gbe ni iyawo l'opin ọsẹ to kọja yii.

Ọkan lara awọn gbajumọ ayaraworan-ile (Architect) to fi ilu Ekoo ṣe ibugbe, Lucky Onojaife ni Joy, gẹgẹ bi a ṣe gbọ.

Akẹkọọ imọ ẹkọ Physiology ni Joy, to si kẹkọọ jade ni fasiti ipinlẹ Delta.

Diẹ lara awọn aworan bi igbeyawo ọhun ṣe lọ ree





No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI