Awa ko darapọ mọ ẹgbẹ oṣelu kankan - Labour - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, November 16, 2023

Awa ko darapọ mọ ẹgbẹ oṣelu kankan - Labour


Ẹgbẹ oṣelu Labour ti sọ pe ko si otitọ ninu awuyewuye to n kaakiri wi pe awọn ti bẹrẹ ipade lati darapọ mọ ẹgbẹ oṣelu kan, to si ni irọ to jinna si otitọ ni.

Akọwe ipolongo ẹgbẹ naa, Obiora Ifoh lo sọrọ yii ninu atẹjade to fi lede lonii, Ọjọbọ, Tọside niluu Abuja.

O ni iroyin ẹlẹjẹ naa ti wọn gbe sita ni lati fi da ẹlẹya awọn silẹ nigboro.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI