Aarẹ orileede Naijiria, Bọla Ahmẹd Tinubu ree nibi pẹlu awọn gomina lorileede yii, nibi imurasilẹ ipade ajọ agbaye, United Nations General Assembly, ẹlẹẹkejidinlọgọrin iru ẹ niluu New York.
Lara awọn gomina to wa nibẹ ni Gomina AbdulRahman AbdulRazaq to jẹ olori awọn gomina Naijiria; Babajide Sanwo-Olu tipinlẹ Ekoo; Ṣeyi Makinde ti ipinlẹ Ọyọ ati awọn miran.
No comments:
Post a Comment