Aarẹ Adetọla EmmanuelKing to jẹ alaṣẹ, apaṣẹ ati oludasilẹ ileeṣẹ Adron Homes and Properties Limited to ba Etsu tiluu Nupe, ipinlẹ Niger yọ fun ti ayẹyẹ igbade ogun ọdun rẹ.
Ile-iṣẹ AWIKONKO MEDIA CHANNEL lo n gbe IROYIN AWIKONKO jade pẹlu ontẹ Ijọba orilẹ-ede Naijiria labẹ ajọ iforukọsilẹ nni, iyẹn CORPORATE AFFAIRS COMMISSION. A fẹ ki ẹyin ti ẹ n ka Iroyin Awikonko mọ daju pe a ko ni i gba ẹnikẹni laaye lati ṣe ẹda iroyin wa, tabi gbe e jade ninu iwe iroyin min in lai gba aṣẹ lọwọ awọn alaṣẹ wa, ẹsẹ ofin la o fi gbe onitọhun. Bẹẹ, a ko ni fẹ ki ẹnikẹni ṣi iroyin wa ka, nitori pe iwadii kikun la n ṣe ka to le gbe iroyin jade, nitori naa, bi ẹ ba ka ifọrọwerọ pẹlu eeyan, ohun ti ẹni naa ba sọ, ki i ṣe awa la sọ ọ, ẹni naa lo sọ bẹẹ. Fun alaye lẹkunrẹrẹ, tabi ipolowo ọja yin, ẹ le kan si wa lori: +2347012342712.
No comments:
Post a Comment