L'Ọjọbọ tii ṣe Tọsidee to kọja yii l'awọn agbaagba niluu Ilọrin, ipinlẹ Kwara ṣabẹwo si Gomina AbdulRahman AbdulRazaq, lati kii ku iṣẹ takuntakun to n ṣe nipa eto idagbasoke ati ilọsiwaju ipinlẹ naa lapapọ.
Lara awọn to lọ ṣabẹwo ọhun ni Alaaji Adefalu Lawal; Alaaji Mustapha Kobe; Alaaji Zubair Olosasa; ati Ọnarebu Abdulgafar Olayemi Ayinla Ayilara.
No comments:
Post a Comment