Gomina AbdulRahman AbdulRazaq t'ipinlẹ Kwara ree to n ba awọn gomina ẹgbẹ rẹ sọrọ nibi ipade awọn alaṣẹ, iyẹn National Executive Council (NEC) to waye niluu Abuja l'Ọjọbọ tii ṣe Tọsidee to kọja yii.
AbdulRazaq to tun jẹ alaga ẹgbẹ awọn gomina ni Naijiria loun pẹlu awọn akẹgbẹ rẹ darapọ mọ Aarẹ Bọla Tinubu, to fi mọ awọn agbaagba ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress (APC) nibi ipade naa.
Fọto ree:
No comments:
Post a Comment