Lasiko ti a pari akojọpọ iroyin yii, inu ipade ikọkọ ni Aarẹ Bọla Ahmẹd Tinubu ati gbogbo awọn olori eleto aabo patapata to ṣẹṣẹ yan fun Naijiria wa.
Ile agbara orileede yii ti a mọ si Aso Rock, eyi to wa niluu Abuja ni ipade ọhun ti n waye.
Igba akọkọ ree ti Tinubu yoo maa ba wọn ṣepade latigba to ti yan wọn s'ipo.
Ẹkunrẹrẹ n bọ laipẹ.
No comments:
Post a Comment