Ileeṣẹ ọlọpaa orileede Naijiria ti kede Ẹbun Oluwarotimi Adelesi gẹgẹ bii ọga ọlọpaa tuntun ti yoo maa tukọ eto aabo n'ipinlẹ Kwara.
Gẹgẹ bi a ṣe gbọ, Ẹbun Adelesi ni obinrin akọkọ ti yoo jẹ ọga ọlọpaa to jẹ obinrinnipinlẹ naa.
Ọga ọlọpaa tuntun yii la gbọ pe yoo ṣiṣẹ papọ pẹlu Gomina AbdulRahman AbdulRazaq t'ipinlẹ naa lati le jẹ ki eto aabo gbopọn sii.
No comments:
Post a Comment