Otitọ ni pe Messi yoo kuro ninu ẹgbẹ agbabọọlu PSG - Galtier - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, June 1, 2023

Otitọ ni pe Messi yoo kuro ninu ẹgbẹ agbabọọlu PSG - Galtier


Alakoso ẹgbẹ agbabọọlu Paris Saint-Germain, Christophe Galtier, ti fidi rẹ mulẹ pe otitọ ni pe Lionel Messi yoo uro ninu ẹgbẹ aa, ni ipari saa yii.
 
Galtier lo tu aṣiri naa ṣaaju ifẹsẹwọnsẹ to n bọ laaarin PSG ati Clermont Foot ninu ifigagbaga Ligue 1 to n bọ lọjọ Abamẹta, Satide.
 
Eyii ni wọn lo tunmọ si pe ifẹsẹwọnsẹ naa ni yoo jẹ eyi to kẹyin ninu eyi ti Messi yoo ti gba bọọlu fun ikọ PSG.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI