Aarẹ Bọla Ahmẹd Tinubu ti kede abẹnugọn ile igbimọ aṣoju-ṣofin Naijiria, Ọnarebu Fẹmi Gbajabiamila gẹgẹ bi olori awọn oṣiṣẹ rẹ.
Tinubu lo kede Gbajabiamila gẹgẹ bi olori awọn oṣiṣẹ rẹ lonii, Ọjọbọ tii ṣe Tọsidee niluu Abuja, lakoko to n ṣe ipade pọ pẹlu awọn olori awọn eleto aabo ni Naijiria.
Ekunrẹrẹ iroyin naa n bọ laipẹ.
No comments:
Post a Comment