Mi o kabamọ pe mo yọ ile ọmọ mi danu lọdun mẹwaa sẹyin - Eve - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Friday, April 21, 2023

Mi o kabamọ pe mo yọ ile ọmọ mi danu lọdun mẹwaa sẹyin - Eve


Ọmọbinrin arẹwa kan to pe orukọ ara rẹ ni Eve Onyedikachukwu ti kọ ọ sori ikanni ayelujara wi pe oun ko kabamọ wi pe oun yọ ile ọmọ oun danu lọdun mẹwaa sẹyin.
 
Eve sọ pe  oun ko le daamu lati gbe oyun, tabi lati gbe ọmọ, idi ree, toun fi yọ ile ọmọ oun danu, lati gbadun aye oun.
 
“Oni yii lo pe ọdun kẹwaa gbako ti mo pinnu lati yọ ile ọmọ mi danu.
 
Mi o kabamọ lati ọdun naa. Ko si idi kan pato lati mu ọmọ wa saye yii, nigba ti o ko ni agbara lati tọju iru ọmọ bẹẹ. Mo ki ara mi ku oriire.”

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI