Ọladipọ Diya ti jade laye ooo - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Sunday, March 26, 2023

Ọladipọ Diya ti jade laye ooo


Olori awọn oṣiṣẹ olori orileede yii tẹlẹ, Oloogbe Ọgagun Sanni Abacha, iyẹn Donaldson Ọladipọ Diya ti jade laye lẹni ọdun mọkandinlọgọrin.
 
Aarọ oni, ọjọ Aiku, Sannde, ọjọ kẹrindinlọgbọn, oṣu kẹta, ọdun 2023 ni ọkan lara awọn ọmọ oloogbe naa, Amofin Oyesinmilọla Diya, kede iku baba rẹ.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI