Lẹyin to b'awọn ọmọ Naijiria sọrọ, Buhari fi Naijiria silẹ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, February 16, 2023

Lẹyin to b'awọn ọmọ Naijiria sọrọ, Buhari fi Naijiria silẹ


Aarẹ Muhammadu Buhari ti ṣetan lati fi orileede Naijiria silẹ lati lọ siluu Addis Ababa, lorileede Ethiopia, pẹlu erongba lati darapọ mọ ipade kan to nii ṣe pẹlu ajọ ilẹ adulawọ, iyẹn African Union, AU.
 
Ipade kan ti wọn pe ni Ordinary Session of the Assembly of the African Union, ẹlẹẹkẹrindinlogoji iru ẹ.
 
A gbọ pe ipade naa ni wọn pe akori ẹ ni “Acceleration of the African Continental Free Trade Area (AfCFTA) Implementation.”

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI