Lojuna lati jẹ k'awọn araalu ri owo naira tuntun gba lati maa na ni gbogbo igba, Gomina AbdulRahman AbdulRazaq ti ṣe ipade papọ pẹlu awọn alaṣẹ banki apapọ lorileede Naijiria, Central Bank of Nigeria (CBN).
Gomina AbdulRazaq la gbọ pe o n ṣiṣẹ takuntakun lati rii pe iya to n jẹ awọn araalu nipa owo naira tuntun naa, eyi ti ko tii kari tete d'opin.
No comments:
Post a Comment