Emi nikan ni aarẹ ti wọn ṣe ilara rẹ ju lagbaye - Buhari - IROYIN AWIKONKO

Thursday, February 23, 2023

demo-image

Emi nikan ni aarẹ ti wọn ṣe ilara rẹ ju lagbaye - Buhari

edddccc_1677144874

Aarẹ Muhammadu Buhari ti orileede Naijiria ti sọ pe oun nikan ni aarẹ ti awọn eeyan ṣe ilara rẹ julọ kaakiri agbaye lakoko yii.
 
Buhari lo sọ eyi di mimọ lakoko to n fa awọn irinṣẹ eto aabo ti owo rẹ le ni biliọnu mejila naira le ileeṣẹ ologun ati ileeṣẹ ọlọpaa lọwọ l'Ọjọru, Wẹsidee, ọsẹ yii.
 
Aarẹ Buhari sọ pe awọn iranwọ toun ti ri gba lati ọdọ awọn ileeṣẹ aladani kaakiri ti jẹ koun di "aarẹ ti wọn n ṣe ilara rẹ lagbaye, toun si tun jẹ iwuri fun ọpọ awọn aarẹ agbaye.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI

Contact Form

Name

Email *

Message *