Eyi l'awọn pata ti gbajugbaja onkọrin agbaye nni, Oloogbe Fẹla Anikulapo n wọ nigba to wa laye, ko to di pe o jade laye.
Awọn apata naa ni wọn ti wa niluu Paris, orileede France nibi ti awọn eeyan kaakiri agbaye ti lọ n fi owo wo o lati mọ bo ṣe ri.
Gbagede igbafẹ aṣa ti a mọ si Musuem, eyi ti wọn sọ lorukọ Fela Museum la gbọ pe awọn eeyan ti lọ n fi owo wo.
Bẹ o ba gbagbe, ọkan pataki lara awọn onkọrin to jẹ obinrin nni, Yẹmi Alade ti fi pata Fẹla kọrin ri, to si ni ogbontarigi ni Fẹla jẹ si awọn pata rẹ [Fela was a legend to his panties" - Yemi Alade.]
No comments:
Post a Comment