Ayẹyẹ aadọrun ọdun: Baba Adeboye gbadura fun mama Ọṣinbajo, igbakeji aarẹ Naijiria - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Friday, February 17, 2023

Ayẹyẹ aadọrun ọdun: Baba Adeboye gbadura fun mama Ọṣinbajo, igbakeji aarẹ Naijiria


Ẹsẹ ko gbero ninu ijọ St Jude Cathedral to wa lagbegbe Ebute-Mẹtta n'ipinlẹ Eko nibi ayẹyẹ ọjọ ibi aadọfun ọdun loke eepẹ, eyi ti mama igbakeji aarẹ Naijiria, Ọjọbọn Yẹmi Ọṣinbajo ṣe.
 
Lara awọn to wa nibẹ ni gbajugbaja olokoowo ilẹ adulawọ, Aliko Dangote; Fẹmi Gbajabiamila; Babajide Sanwo-Olu; Ibikunle Amosun; Dapọ Abiọdun; Pasitọ Adeboye ati awọn mi in.
 
Ọjọbọ, Tọsidee, ọsẹ yii ni ayẹyẹ naa waye, nibi ti Baba Adeboye ti ijọ Ridiimu ti gbadura.






No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI