Òjò àkọ́kọ́ nínú ọdún 2023 balẹ̀ jẹ́: ìjí jà, ilé wó, ṣọ́ọ̀ṣì lulẹ̀, dúkìá ṣòfò - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Tuesday, January 24, 2023

Òjò àkọ́kọ́ nínú ọdún 2023 balẹ̀ jẹ́: ìjí jà, ilé wó, ṣọ́ọ̀ṣì lulẹ̀, dúkìá ṣòfò


Bo tilẹ jẹ pe adura ọpọ awọn eeyan kaakiri orileede Naijiria ni pe ki ojo tete bẹrẹ lọdun 2023 ti a wa yii, ki ooru buruku to n mu le kasẹ nilẹ, ṣugbọn ijamba ni ojo naa fa l'awọn agbegbe kan, paapaa n'ipinlẹ Ogun.

Nibi ti awọn kan ti jo, ti wọn n yọ, ti wọn si n kọrin ọpẹ, nibẹ l'awọn miran ti n banujẹ lori awọn dukia wọn to ṣofo danu.
 
Agbegbe ti wọn n pe ni Mọbalufọn, Latogun niluu Ijẹbu Ode, ipinlẹ Ogun ni iji ojo naa ti ṣọṣẹ nla.
 
Lara awọn dukia to farakaaṣa ni ṣọọṣi, ile ẹkọ, ile, fẹnsi, ati bẹẹbẹẹlọ.
 
📸: Ijebu Rewa - Facebook












No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI