Mi o le ṣe otitọ pẹlu obinrin kan ṣoṣo lailai - Don Jazzy sọrọ, ilẹ kun - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Tuesday, January 10, 2023

Mi o le ṣe otitọ pẹlu obinrin kan ṣoṣo lailai - Don Jazzy sọrọ, ilẹ kun


Gbajugbaja olori takasufee nni, Michael Collins Ajereh, ti ọpọ awọn eeyan mọ si Don Jazzy ti jẹ ko di mimọ pe oun ko le ṣe deedee, bẹẹ loun ko tun le ṣe otitọ pẹlu obinrin kan ṣoṣo.
 
O loun kii ṣe iru ọkunrin to n ni iyawo kan ṣoṣo.

Don Jazzy lo sọrọ yii nibi ifọrọwerọ to ṣe pẹlu gbajugbaja sọrọsọrọ oloyinbo nni, Nedu lori eto Frankly Speaking, to si loun ko tii ṣe deedee ri pẹlu obinrin kan ṣoṣo.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI