Ọna ara ọtọ ni ẹgbẹ oṣelu Peoples Democratic Party, PDP tun gbe ipolongo idibo wọn gba laipẹ yii, pẹlu bi gbajugbaja Sẹnetọ tẹlẹ nni, Dino Melaye ṣe fi oludije sipo Aarẹ labẹ asia ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress, APC Aṣiwaju Bọla Ahmẹd Tinubu ṣe ẹlẹya ita gbangba.
Ninu fọnran ti Dino Melaye gbe soju opo Fesibuuku ati Insitagiraamu rẹ laipẹ yii, lati rii to n ṣubu lati maa fi ṣapejuwe bi Tinubu yoo ṣe lulẹ ninu eto idibo to n bọ lọna.
No comments:
Post a Comment