Kwara 2023: Ilana gomina ana, Ahmẹd ni maa tẹle bi mo ba di gomina - Yaman ṣeleri f'awọon araalu - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Wednesday, November 30, 2022

Kwara 2023: Ilana gomina ana, Ahmẹd ni maa tẹle bi mo ba di gomina - Yaman ṣeleri f'awọon araalu


Oludije s'ipo gomina labẹ asia ẹgbẹ oṣelu Peoples Democratic Party, PDP nipinlẹ Kwara, Abdullahi Yaman ti ṣeleri f'awọn araalu wi pe ilana ti gomina ana n'ipinlẹ naa, Abdulfatai Ahmẹd fi silẹ loun yoo tẹle.
 
Yaman lo sọ eyi di mimọ lakoko to n b'awọn eeyan rẹ sọrọ nijọba ibilẹ Ariwa Kwara lọjọ Iṣẹgun, Tusidee ana.
 
Ọkunrin naa to jade du ipo gomina labẹ asia ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress, APC l'ọdun 2019 sọ pe ọna toun nigbagbọ ninu ẹ ni gomina ana naa, Ahmẹd tọ, to si loun ko ni yẹ ninu ẹ.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI