Ọkan pataki lara awọn ọmọ ẹgbẹ oṣelu Social Democratic Party, SDP, Abdulmajeed Hamza Dọlapọ ti kọwe s'awọn alakoso ẹgbẹ wi pe oun ko ṣẹgbẹ naa mọ.
Dọlapọ, ẹni to ti figba kan ri jẹ oludije s'ipo oṣelu ninu ẹgbẹ naa lo kọwe f'ẹgbẹ silẹ ninu awọn iwe meji to tẹ wa lọwọ lọtọọtọ.
Lẹta naa to tẹ wa lọwọ ree:
No comments:
Post a Comment