Alaga ẹgbẹ oṣelu PDP tẹlẹri jade laye - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Saturday, October 8, 2022

Alaga ẹgbẹ oṣelu PDP tẹlẹri jade laye


Iroyin to tẹ wa lọwọ bayii ti f'idi rẹ mulẹ pe alaga ẹgbẹ oṣelu
Peoples Democratic Party (PDP) nigba kan ri, Vincent Ogbulafor ti jade laye lẹni ọdun mẹtalelaadọrin, 73.
 
Goddy Uwazurike, to jẹ agbẹjọro oloogbe ati ẹni to sunmọ oloogbe naa daa lo f'idi iroyin yii mulẹ, to si jẹ ka mọ pe ilu Canada ni baba naa ku si l'Ọjọbọ, Tọside, ọsẹ yii.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI