Ile ẹjọ apapọ ti wọn pe ni National Industrial Court ti paṣẹ pe ki gbogbo awọn olukọọ ati oṣiṣẹ ile ẹkọ fasiti ti wọno wa labẹ asia ẹgbẹ Academic Staff Union of Universities (ASUU) kaakiri orileede Naijiria pada s'ẹnu iṣẹ wọn lai fi akoko ṣofo rara.
Oni, Ọjọru, Wẹsidee ni ile-ẹjọ naa paṣẹ ọhun labẹ ofin ti Trade Dispute Act and National Interest, abala kejidinlogun sọ pe ki gbogbo wọn pada sẹnu iṣẹ.
Nigba to n gbe idajọ naa kalẹ, Onidajọ Polycap Hamman paṣẹ pe ki iyanṣẹlodi naa d'opin ni kiakia.
No comments:
Post a Comment