Beeyan ba ṣe rere, ka wi, beeyan ba si ṣe ohun to ku diẹ kaato, a ni lati sọ faraye, eyi lo fa apilẹkọ ti Ọgbẹni Lateef Ọlamilekan kọ nipa Gomina AbdulRahman AbduRazaq t'ipinlẹ Kwara.
Ninu apilẹkọ ọhun lo ti yannanaa awọn aṣeyọri Gomina AbdulRazaq laaarin ọdun mẹta to gba ijọba kuro lọwọ awọn alatako.
Ẹ ka ẹkurẹrẹ rẹ nibi Ẹ jẹ ka 'Buga Wọn' fun Gomina AbdulRazaq - Lateef Ọlamilekan
No comments:
Post a Comment