Ile igbimọ aṣofin agba orileede Naijiria ti fi ontẹ lu Onidajọ Olukayọde Ariwoọla gẹgẹ bi adajọ agba pata fun Naijiria, lẹyin ti Aarẹ Buhari ti fi orukọ rẹ ranṣẹ ni nnkan bi oṣu mẹta sẹyin.
Eyi waye lẹyin ti igbimọ ti pari ayẹwo daadaa.
Oni ni ile igbimọ aṣofin agba sọ pe ki Ariwoọla tẹsiwaju gẹgẹ bi adajọ agba.
No comments:
Post a Comment