B'awọn kan ṣe n gbe ara wọn ṣanlẹ, l'awọn kan n bu sẹkun, nibi eto isinku gbajugbaja sọrọsọrọ nni, Abiọdun Ọrọpọ ti wọn tun n pe ni Oyinlọmọ Jọọjọọ Alaaji.
Alẹ ọjọ Abamẹta, Satide to kọja, iyẹn ọjọ ọdun Ileya ni ọkunrin naa dagbere faye lẹyin aisan rampẹ.
Ọjọ Aiku, Sannde ijẹta ni wọn sinku rẹ ni ilana musulumi.
Bayii ni wọn ṣe sin oku naa, ati bi awọn eeyan ṣe barajẹ.
No comments:
Post a Comment