Ahmẹd Musa, agbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà fún ẹgbẹ̀rún márùn-ún èèyàn ni ẹgbẹ̀rún lọ́nà ogún náírà nílùú Jos - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Monday, June 27, 2022

Ahmẹd Musa, agbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà fún ẹgbẹ̀rún márùn-ún èèyàn ni ẹgbẹ̀rún lọ́nà ogún náírà nílùú Jos


Lonii, Balogun ikọ ẹgbẹ agbabọọlu agba fun orileede Naijiria, iyẹn Super Eagles, Ahmẹd Musa lo ti ṣe ọpọlọpọ bẹbẹ, pẹlu bo ṣe fi obitibiti owo ta awọn eeyan lọrẹ, pẹlu erongba lati mu wọn kuro ninu iṣẹ ati oṣi.

Awọn eeyan ti ko din ni ẹgbẹrun marun-un ni iroyin fi to wa leti pe Ahmẹd Musa fun ni ẹgbẹrun lọna ogun naira.

Ilu Jos ni Musa ti ṣe bẹbẹ naa, eyi ti awọn to n tọrọ baara, awọn alaisan, awọn to ku diẹ kaato fun, awọn olokoowo kekeeke, to fi mọ awọn to gba ẹbun ẹkọ ọfẹ.


No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI