Adajọ agba Naijiria kọwe f'ipo silẹ lojiji - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Monday, June 27, 2022

Adajọ agba Naijiria kọwe f'ipo silẹ lojiji


Iroyin to tẹ AWIKONKO lọwọ laipẹ yii fi f'idi rẹ mulẹ wi pe adajọ agba orileede Naijiria, Onidajọ Tanko Muhammad ti kọwe f'ipo rẹ silẹ, to si ni asiko ti to f'oun lati lọ sinmi.
 
Ẹkunrẹrẹ iroyin naa n bọ laipẹ.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI