Igbakeji Aarẹ orileede yii, Ọjọgbọn Yẹmi Ọṣinbajo lonii, ọjọ Aje, Mọnde ti ṣe abẹwo si Gomina AbdulRahman AbdulRazaq ti ipinlẹ Kwara lori eto idibo to n bọ lọna.
Nibi abẹwo ọhun lo ti ya lọ ṣe abẹwo si Ẹmir tilu Ilọrin, Ọmọwe Ibrahim Sulu-Gambari, ẹni to tun jẹ alaga ẹgbẹ àwọn ọba alaye n'ipinlẹ naa.
Diẹ ree lara fọto abẹwo ọhun:
No comments:
Post a Comment