O tan o! Buhari tu aṣiri ẹni ti yoo gbe ijọba le lọwọ l'ọdun 2023 - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Tuesday, May 3, 2022

O tan o! Buhari tu aṣiri ẹni ti yoo gbe ijọba le lọwọ l'ọdun 2023


Aarẹ Muhammadu Buhari ti orileede yii ti sọ pe ẹnikẹni ti awọn ọmọ Naijiria ba dibo yan loun yoo gbe ijọba fun, ati pe oun ko lọwọ si oludije kankan lasiko yii.

Nigba to n dahun ibeere lati ọdọ awọn akọroyin niluu Abuja, lẹyin irun Yidi ti aawẹ Ramadaani to ṣẹṣẹ pari yii ni Aarẹ Buhari sọ pe oun ko ti ni erongba kankan lati bu ọwọ lu oludije kankan fun idibo apapọ ọdun 2023.

"Ẹni ti awọn ọmọ Naijiria ba dibo yan ni maa gbe ijọba le lọwọ."

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI