Ẹmir tilu Ilọrin, Ọmọwe Ibrahim Sulu-Gambari ti sọ pe awọn ko ti i fẹ ẹlomiran nipo gomina ipinlẹ Kwara lasiko yii, bi ko ṣe pe ki AbdulRahman AbdulRazaq maa ba iṣẹ rere rẹ lọ fun saa keji.
Ọmọwe Sulu-Gambari, ẹni to tun jẹ alaga igbimọ awọn ọba alaye n'ipinlẹ Kwara lo sọ eyi di mimọ pe yii, to si ni ohun nnkan toun ba ni n'pa loun yoo ṣe lati ri pe AbdulRazaq pada fun saa keji, ko le pari awọn akanṣe iṣẹ to dawọ le.
No comments:
Post a Comment