Mi o mọ nnkankan nipa iku Oluwabamiṣe - Awakọ sọrọ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Tuesday, March 8, 2022

Mi o mọ nnkankan nipa iku Oluwabamiṣe - Awakọ sọrọ


Ọgbẹni Nice Andrew Omininikoron, ẹni ọdun mẹtadinlogoji to wa bọọsi BRT ti Oluwabamiṣe Ayanwọle to doloogbe laipẹ yii wọ ti ṣalaye wi pe oun ko mọ nnkankan nipa iku ẹ, ati pe awọn adigunjale ni wọn da oun lọna.
 
Nice sọ pe ṣe lawọn adigunjale naa wọ Oluwabamiṣe bọ silẹ ninu bọọsi oun, eyi toun fi ri anfaani lati na papa bora.
 
Alaye rẹ ree lẹkunrẹrẹ
 

 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI